Tope Alabi - ERU OGO RE BAMI OLUWA

Music 5 years ago

Tope Alabi - ERU OGO RE BAMI OLUWA

Here is a 13 April 2012 released 6-Tracks solo album by Tope Alabi titled “Agbelebu“.

Just as most of her fans knows that Tope Alabi is always at her best to deliver great inspirational gospel songs in her dialect, the album was released under Gospel Vibes Ltd. record label.

Listen, Share, Buy, Stream and enjoy

Eru Ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo


Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
1.
Boti n gbe ninu ogo
o n Sogo Lori ite o
ogo lo wo laso
Oloju ogo ni
eda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka
baba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo.
2.
Boti leruniyi to
ite idajo taanu togo
ogo otun iseju si iseju
ewa ti o lakawe
nigbogbo igba sigba
Ododo logo re
awon orile -ede gbogbo nsola Lori ogo re
3.
Olorun to ta sanmo pelu ogo
Iwo lasaju ologo to leruniyi iba baba iba
call: alogoleru
response: toloke
call: eleruniyi
response: tonile
call: onile ola
response: alade ogo
call: ofi kikida ogo
response: sagbeji ara
call: ogo eleru
response: ologo gbanla
Jehovah oba, ologo
aye mi n wari ogo re.
Artiste: Tope Alabi
If you did not see a download button, kindly turn off "your ad-blocker" / "Data Savings" or try a different Browser like "Firefox Browser". After turning it off, reload page.

Previous Track In Album

Tope Alabi - Orun Oun Aye

Next Track In Album

Tope Alabi - TIRE NI OLUWA

What's your rating?
0
{{ratingsCount}} Votes


Related music
Oluwabukola Ilesanmi – My Secret Place
Music | 2 days ago

Oluwabukola Ilesanmi – My Secret Place

Dunsin Oyekan – Ogo Ft. Theophilus Sunday
Music | 2 days ago

Dunsin Oyekan – Ogo Ft. Theophilus Sunday

Ugoccie – Ogo M
Music | 2 weeks ago

Ugoccie – Ogo M

Oluwatoyin Adesemowo – Beginning And The End
Music | 3 weeks ago

Oluwatoyin Adesemowo – Beginning And The End