Tope Alabi - Nigbati Mo Ro

1 year ago

Off the 2007 album by Tope Alabi titled Angeli Mi, comes a whooping 9-tracks singles from the Yoruba Gospel Musician.

The album is majorly Jazz and was released and licensed under NPC Records.Audioworks.

Listen, Share and Enjoy

Attached File:

Lati inu oyun
Titi di omo owo o
Igba mo wa lomo owo

Awon ota gba wipe iku o pa mi

mo ra ko de ile awon ti o fe kin waye rara
Baba o sho mi, ore re yi ko lakawe

Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi
Titi mo fi wa di agbalagba o

Igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi
Mo wa ri pe oga pupo

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi, mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi, mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Ogun ti eniyan ja ni agba, o poju Ogun ewe lo
Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi mo ooo
Oju ogun laye je feni to waye o se rere
Mo wa ro inu jinle
Aanu re lori aye mi
Emi ri pe o ga o, pupo

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi, mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi, mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi da
Iya to je mi, o ke ko je ki gbe o, baba o seun.
...olusegun fun mi iwo ni
Iwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwo
O gbe mi so ke gogoro, Osuba re o baba
eyi ni mo se isiro titi, ognon ori mi ko gbe

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi, mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
mori pe oga, more ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi, mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Previous Track In Album

Tope Alabi - E Gbe Ga

Next Track In Album

Tope Alabi - Wa B'eru Re Ni Bode

Related music
Music
Tope Matthew – Do Me Well
1 month ago
Music
Eben – Nothing Is Impossible Ft Tope Alabi
2 months ago
Music
Eben – Nothing Is Impossible ft. Tope Alabi
2 months ago
Music
Tope Alabi – Can’t Believe (Tribute To Ibidunni Ighodalo)
3 months ago