Tope Alabi - Orun Oun aye

2 years ago

Here is a 13 April 2012 released 6-Tracks solo album by Tope Alabi titled “Agbelebu“.

Just as most of her fans knows that Tope Alabi is always at her best to deliver great inspirational gospel songs in her dialect, the album was released under Gospel Vibes Ltd. record label.

Listen, Share, Buy, Stream and enjoy

Attached File:

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Didara orun oun so togo Re o Olorun
Ewa Re to yi aye ka n so togo Re bo ti po to
Gbogbo eda eranko at'ewebe n yin O o
Ise owo Re gbogbo lo n keyin le, won yin O o Baba

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kada orun
Ika ese Re o n han l'ori apata
Esin Re n fogo yan l'ori awo okun o Olola nla
Kini o waa se mi ti n o jokeleyo
Ti n o ni le juba Re Oba

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Gbogbo eemi inu mi o n yin O yato Olorun mi
Iwo to mu la ina koja to fi mumi goke
Kini mba fi fun O
Kini mo tosi ninu Oreofe ti mo rigba lodo Re
Oba ye mida majemu lati nu'mole
Oro ye ye osise
Oba ti ki n dale oro Ore
Iwariri ni n o fi juba Re

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Next Track In Album

Tope Alabi - ERU OGO RE BAMI OLUWA

Related music
Roseline Effiong – Agbara Orun ft. Sis. Titi Idowu
Music

Roseline Effiong – Agbara Orun ft. Sis. Titi Idowu

1 week ago
Charze – Aye O Pe Meji ft. Barry Jhay
Music

Charze – Aye O Pe Meji ft. Barry Jhay

1 month ago
Vida-soul – Aye Suka (Original Mix)
Music

Vida-soul – Aye Suka (Original Mix)

1 month ago
Ayesem – Bars Of Realities
Music

Ayesem – Bars Of Realities

4 months ago