Tope Alabi - You Are Worthy

2 years ago

Veteran Gospel Singer Tope Alabi is gearing up to release “Yes and Amen“, the follow-up to her 2014 LP – Oruko TunTun .

Attached File:

hmmmmm
ohhhhh
ehhhhhhhyou are worthy, you are worthy, you are worthy of my praise.(2ce)
eleburuike oooo, oranmonisefayati oooo, aranibanilo ooooo,
you are worthy.oba to gba mi la o,
olowo ina oooo, iwo nikan logo ye ooo you are worthy.
lion of the tribe of judea, kinging in his majesty,
ruler of the universe,
i tremble at your feet(2ce)worthy of our worship.
olola to ga ju lo, oloro to poju lo, ologo to ga ju you are worthy,
oba to ju gbogbo oba lo,
ijoba ni bi gbogbo olori aye isale ile alainipekun ni o.
oforun nikan se kiki da wura,
oda orun pelu aye pelu ara oto ebo mi aji to la mo gbo su ba fogo ra
bale ibeere ogo arin ogo olunkangun igbeyin ogo eniti gbogbo aye yio
pada wa bo kabiesi oooo araye koba ni kabiesi won ni kade pe lori ki
bata pe lese o iwo nikan ni kabiesi ta o gbodo so pe kade pe lori fun
ewo a o gbodo ni ki bata pe lese lailai sade ta o
mo gba to gori e se bata ta o mo gba to wo ese re

Next Track In Album

Tope Alabi - Halleluyah

-

Related music
Music
Jay Worthy Ft. Krayzie Bone & Shlohmo – Ride
4 weeks ago
Music
Flee Lord Ft. Jay Worthy & TND Riley – The Beginning
1 month ago
Music
Eben – Nothing Is Impossible Ft Tope Alabi
1 month ago
Music
Eben – Nothing Is Impossible ft. Tope Alabi
1 month ago